Áàpù Aláàgbéká
Àkójọpọ̀ àwọn áàpù ọ̀fẹ́ elédèjèdè tí ń ṣiṣẹ́ láìsí Ayélujára. Tí àwọn ènìyàn tí ń lòó ní àwọn àwùjọ ti dán an wò, Hesperian ṣe àṣírí ìkọ̀kọ̀ rẹ ní àkọ́kọ́.
Àkójọpọ̀ àwọn áàpù ọ̀fẹ́ elédèjèdè tí ń ṣiṣẹ́ láìsí Ayélujára. Tí àwọn ènìyàn tí ń lòó ní àwọn àwùjọ ti dán an wò, Hesperian ṣe àṣírí ìkọ̀kọ̀ rẹ ní àkọ́kọ́.
A wà ní ìlera síi bí a bá fúnra wa pinnu ìgbà tí a fẹ́ ní ìbálòpọ̀, ìgbà tí a fẹ́ lóyún, àti ìgbà tí a fẹ́ bímọ. Àwọn áàpù Hesperian elédèjèdè tó ṣeé fi sí ojúṣe ní àwọn àlàyé ìlera ìbímọ tó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé àti àwọn ohun èlò tó lè ran ni lọ́wọ́. Lẹ́yìn gbígbàá sílẹ̀, àwọn áàpù yìí ń ṣiṣẹ́ láìsí ayélujára tàbí owó àsopọ̀ mọ́ orí ayélujára. Lò wọ́n láti mú ìpinnu tí yíò ṣe ìdánilójú àbáyọrí ìlera síi fún ara rẹ, àwọn olólùfẹ́ rẹ, àti àwùjọ rẹ.
Áàpù Ìṣẹ́yún Láìséwu
Gba àlàyé, lẹ́kùnrẹ́rẹ́, ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé lórí ìṣẹ́yún láìséwu. Ṣe àfiwé àwọn ọ̀nà ìṣẹ́yún, lo aṣèṣirò oyún, kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tàbí kí o dáhùn àwọn àkólékàn tó wọ́pọ̀ pẹ̀lú ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ FAQ wa. Ó wà fún ìlò àwọn oníkálukú, òṣìṣẹ́ ìlera, àti àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́, áàpù Ìṣẹ́yún Láìséwu kéré láti gbà sílẹ̀ (kò tó 40mb), tí a sì pèsè láti ṣe àrídájú àṣírí àwọn tí ń lòó.
Àwọn èdè tó wà
- Afaan Oromoo
- Amharic
- English
- Español
- Français
- Igbo
- Kinyarwanda
- Kiswahili
- Luganda
- Português
- Yoruba
O lè yípadà láti inú éyíkéyìí àwọn èdè 11 yìí sí òmíràn nígbàkugbà.
Family Planning app
Developed for frontline health workers, local leaders, and peer promoters, this app is filled with clear photos and illustrations, easy-to-understand information, and interactive tools to support conversations about reproductive health. Family Planning covers essential topics for counseling including how each method is used, how well it prevents pregnancy, how easily it can be kept secret, and side effects.
LANGUAGES AVAILABLE
• Afaan Oromoo
• Amharic
• English
• Spanish
• French
• Kinyarwanda
• Kiswahili
• Luganda
• Portuguese
Change between all 9 languages at any time.
Safe pregnancy and birth app
Safe Pregnancy and Birth provides accurate, easy-to-understand information on pregnancy, birth, and care after birth. Clear illustrations and plain language make this award-winning app practical and user-friendly for community health workers, midwives, and individuals and their families. Free and small to download, this app works offline without a data plan.
Language choices in the Safe Pregnancy and Birth app: English, Español. Change between both languages at any time.