Áàpù Ìṣẹ́yún Láìséwu
Àkójọpọ̀ àwọn áàpù ọ̀fẹ́ elédèjèdè tí ń ṣiṣẹ́ láìsí Ayélujára. Tí àwọn ènìyàn tí ń lòó ní àwọn àwùjọ ti dán an wò, Hesperian ṣe àṣírí ìkọ̀kọ̀ rẹ ní àkọ́kọ́.
Gba ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé tó pé, tó sì rọrùn láti lò lórí ọ̀nà àti ṣẹ́yún. Ti a kọ ní ọ̀nà tó rọrùn láti kà, àti ní èdè tí kò dá ni lẹ́bi, áàpù Ìṣẹ́yún Láìséwu náà tún lè ràn àwọn tó nílò tàbí tí ń fún ni ní ìtọjú lẹ́yìn ìṣẹ́yún. Gbàá sílẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́ tàbí kí o lòó lórí ojú ewé ayélujára wà.
Àwọn èdè tó wà tí o lè yàn lórí ààpù náà ní Afaan Oromoo, Amharic, English, Español, Français, Igbo, Kinyarwanda, Kiswahili, Luganda, Português, àti Yoruba. O lè yípadà láti inú éyíkéyìí àwọn èdè 11 yìí sí òmíràn nígbàkugbà.
ÀÀPÙ YÌÍ KÌÍ ṢE ÀGBÀSÍLẸ̀ ÀWỌN ÀLÀYÉ ÀṢÍRÍ NÍPA RẸ!
O lè wo Àlàkalẹ̀ Àṣírí Áàpù orí ẹ̀rọ Aláàgbéká wà níbí

O Lè Wo Àlàkalẹ̀ Àṣírí Áàpù Orí Ẹ̀rọ Aláàgbéká Wà Níbí
Wo fídíò yìí
Gba áàpù náà sílẹ̀
Lo áàpù náà lórí ayélujára
Lo áàpù náà lórí ojú ewé yìí lórí aṣàwákiri orí ayélujára rẹ ní àì gbàá sílẹ̀
Lo áàpù náà lórí ojú ewé yìí lórí aṣàwákiri orí ayélujára rẹ ní àì gbàá sílẹ̀
Inú ààpù Ìṣẹ́yún Láìséwu náà:
-
Ṣàwárí àpèjúwe kedere tó pé nípa àwọn ọ̀nà ìṣẹ́yún: ìṣẹ́yún pẹ̀lú egbògi, oǹfà, àti fífẹ̀ẹ́ àti kíkóo jáde
-
Gba àlàyé nípa àwọn òdiwọn tó tọ́ àti àwọn ọ̀nà láti kóró egbògi misoprostol (pẹ̀lú àti láìsí mifepristone) fún ìṣẹ́yún pẹ̀lú egbògi ní onírúurú ọ̀sẹ̀
-
Kọ́ nípa àwọn ohun tó yẹ kí o máa retí láàrín àti lẹ́yìn ìṣẹ́yún, pẹ̀lú ìdáhùn rẹ sí àwọn àmì ìkìlọ bí wọn bá ṣẹlẹ̀
-
Múra kí o sì gbáradì fún ìṣàkóso ìṣẹ́yún pẹ̀lú àtẹ àwọn ojúṣe, kí o sì ṣàwárí àwọn àbá fún bí o ti lè ṣe ìtọ́jú ara àti ìmọ̀lára rẹ
-
Ṣe àyẹ̀wò àlàyé “fún orílẹ̀-èdè rẹ” láti ṣàwárí àwọn àjọ tó lè ràn ọ́ lọ́wọ́ àti àwọn àsopọ tààrà sí àwọn ìlànà òfin tó rọ̀ mọ́ọ
-
Dáhùn àwọn ìbéèrè kí o sì dáhùn àwọn àkólékàn tó wọ́pọ̀ pẹ̀lú ààyè ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ FAQ
-
Tẹ́tí sí àwọn àlàyé pẹ̀lú ojúṣe kíkà sókè nígbà tí o bá ń lo ààpù náà ní Gẹ̀ẹ́sì, Spáníìṣì, Pọtugí tàbí Faransé
A ṣe ètò Ìṣẹ́yún Láìséwu láti ṣe àrídájú ààbò àṣírí rẹ. Bí o bá fẹ́ gba ààpù náà sílẹ̀ fún lílò, Ìṣẹ́yún Láìséwu kò tó 40mb ó sì ń ṣiṣẹ́ dáradára láìsí détà tàbí ààyè sórí ayélujára. Lórí ẹ̀rọ fóònù rẹ, àmì ààpù náà yíò hàn gẹ́gẹ́ bíi “IL” nìkan.
Atọ́nisọ́nà ààpù Ìṣẹ́yún Láìséwu kíákíá
Tẹ ìtọ́nisọ́nà náà jáde
Àwọn ìlànà fún àtòpọ̀ kíákíá
Tẹ àwọn àwòrán tó wà ní ìsàlẹ̀ láti múu tóbi